Quran with Yoruba translation - Surah An-Nahl ayat 6 - النَّحل - Page - Juz 14
﴿وَلَكُمۡ فِيهَا جَمَالٌ حِينَ تُرِيحُونَ وَحِينَ تَسۡرَحُونَ ﴾
[النَّحل: 6]
﴿ولكم فيها جمال حين تريحون وحين تسرحون﴾ [النَّحل: 6]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọ̀ṣọ́ tún ń bẹ fun yín lára wọn nígbà tí ẹ bá ń dà wọ́n lọ (sí ilé wọn) àti nígbà tí ẹ bá ń kó wọn jáde lọ jẹko |