Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 32 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿وَلَا تَقۡرَبُواْ ٱلزِّنَىٰٓۖ إِنَّهُۥ كَانَ فَٰحِشَةٗ وَسَآءَ سَبِيلٗا ﴾
[الإسرَاء: 32]
﴿ولا تقربوا الزنا إنه كان فاحشة وساء سبيلا﴾ [الإسرَاء: 32]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ má ṣe súnmọ́ àgbèrè. Dájúdájú ó jẹ́ ìwà burúkú. Ó sì burú ní ojú ọ̀nà |