Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 43 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿سُبۡحَٰنَهُۥ وَتَعَٰلَىٰ عَمَّا يَقُولُونَ عُلُوّٗا كَبِيرٗا ﴾
[الإسرَاء: 43]
﴿سبحانه وتعالى عما يقولون علوا كبيرا﴾ [الإسرَاء: 43]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Mímọ́ ni fún Un. Ó sì ga ní gíga t’ó tóbi tayọ ohun tí wọ́n ń wí (ní àìda nípa Rẹ̀) |