×

So fun awon erusin Mi pe ki won so oro eyi t’o 17:53 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Isra’ ⮕ (17:53) ayat 53 in Yoruba

17:53 Surah Al-Isra’ ayat 53 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 53 - الإسرَاء - Page - Juz 15

﴿وَقُل لِّعِبَادِي يَقُولُواْ ٱلَّتِي هِيَ أَحۡسَنُۚ إِنَّ ٱلشَّيۡطَٰنَ يَنزَغُ بَيۡنَهُمۡۚ إِنَّ ٱلشَّيۡطَٰنَ كَانَ لِلۡإِنسَٰنِ عَدُوّٗا مُّبِينٗا ﴾
[الإسرَاء: 53]

So fun awon erusin Mi pe ki won so oro eyi t’o dara julo. Dajudaju Esu yoo maa da yanpon-yanrin sile laaarin won. Dajudaju Esu je ota ponnbele fun eniyan

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وقل لعبادي يقولوا التي هي أحسن إن الشيطان ينـزغ بينهم إن الشيطان, باللغة اليوربا

﴿وقل لعبادي يقولوا التي هي أحسن إن الشيطان ينـزغ بينهم إن الشيطان﴾ [الإسرَاء: 53]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Sọ fún àwọn ẹrúsìn Mi pé kí wọ́n sọ ọ̀rọ̀ èyí t’ó dára jùlọ. Dájúdájú Èṣù yóò máa dá yánpọn-yánrin sílẹ̀ láààrin wọn. Dájúdájú Èṣù jẹ́ ọ̀tá pọ́nńbélé fún ènìyàn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek