×

Oluwa re nimo julo nipa awon t’o n be ninu awon sanmo 17:55 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Isra’ ⮕ (17:55) ayat 55 in Yoruba

17:55 Surah Al-Isra’ ayat 55 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 55 - الإسرَاء - Page - Juz 15

﴿وَرَبُّكَ أَعۡلَمُ بِمَن فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِۗ وَلَقَدۡ فَضَّلۡنَا بَعۡضَ ٱلنَّبِيِّـۧنَ عَلَىٰ بَعۡضٖۖ وَءَاتَيۡنَا دَاوُۥدَ زَبُورٗا ﴾
[الإسرَاء: 55]

Oluwa re nimo julo nipa awon t’o n be ninu awon sanmo ati ile. Dajudaju A ti se oore ajulo fun apa kan awon Anabi lori apa kan. A si fun (Anabi) Dawud ni Zabur

❮ Previous Next ❯

ترجمة: وربك أعلم بمن في السموات والأرض ولقد فضلنا بعض النبيين على بعض, باللغة اليوربا

﴿وربك أعلم بمن في السموات والأرض ولقد فضلنا بعض النبيين على بعض﴾ [الإسرَاء: 55]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Olúwa rẹ nímọ̀ jùlọ nípa àwọn t’ó ń bẹ nínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀. Dájúdájú A ti ṣe oore àjùlọ fún apá kan àwọn Ànábì lórí apá kan. A sì fún (Ànábì) Dāwūd ní Zabūr
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek