Quran with Yoruba translation - Surah Al-Isra’ ayat 81 - الإسرَاء - Page - Juz 15
﴿وَقُلۡ جَآءَ ٱلۡحَقُّ وَزَهَقَ ٱلۡبَٰطِلُۚ إِنَّ ٱلۡبَٰطِلَ كَانَ زَهُوقٗا ﴾
[الإسرَاء: 81]
﴿وقل جاء الحق وزهق الباطل إن الباطل كان زهوقا﴾ [الإسرَاء: 81]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Òdodo dé. Irọ́ sì sá lọ. Dájúdájú irọ́ jẹ́ ohun tí ó máa sá lọ.” |