×

Nigba ti awon odokunrin naa kora won sinu iho apata, won so 18:10 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Kahf ⮕ (18:10) ayat 10 in Yoruba

18:10 Surah Al-Kahf ayat 10 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 10 - الكَهف - Page - Juz 15

﴿إِذۡ أَوَى ٱلۡفِتۡيَةُ إِلَى ٱلۡكَهۡفِ فَقَالُواْ رَبَّنَآ ءَاتِنَا مِن لَّدُنكَ رَحۡمَةٗ وَهَيِّئۡ لَنَا مِنۡ أَمۡرِنَا رَشَدٗا ﴾
[الكَهف: 10]

Nigba ti awon odokunrin naa kora won sinu iho apata, won so pe: “Oluwa wa, fun wa ni ike lati odo Re, ki O se imona ni irorun fun wa ninu oro wa.”

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إذ أوى الفتية إلى الكهف فقالوا ربنا آتنا من لدنك رحمة وهيئ, باللغة اليوربا

﴿إذ أوى الفتية إلى الكهف فقالوا ربنا آتنا من لدنك رحمة وهيئ﴾ [الكَهف: 10]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Nígbà tí àwọn ọ̀dọ́kùnrin náà kóra wọn sínú ihò àpáta, wọ́n sọ pé: “Olúwa wa, fún wa ní ìkẹ́ láti ọ̀dọ̀ Rẹ, kí O ṣe ìmọ̀nà ní ìrọ̀rùn fún wa nínú ọ̀rọ̀ wa.”
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek