×

Nigba ti awon mejeeji re koja (ibi ti odo meji ti pade), 18:62 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Kahf ⮕ (18:62) ayat 62 in Yoruba

18:62 Surah Al-Kahf ayat 62 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Kahf ayat 62 - الكَهف - Page - Juz 15

﴿فَلَمَّا جَاوَزَا قَالَ لِفَتَىٰهُ ءَاتِنَا غَدَآءَنَا لَقَدۡ لَقِينَا مِن سَفَرِنَا هَٰذَا نَصَبٗا ﴾
[الكَهف: 62]

Nigba ti awon mejeeji re koja (ibi ti odo meji ti pade), o so fun omo-odo re pe: "Fun wa ni ounje osan wa. Dajudaju a ti ko wahala ninu irin-ajo wa yii

❮ Previous Next ❯

ترجمة: فلما جاوزا قال لفتاه آتنا غداءنا لقد لقينا من سفرنا هذا نصبا, باللغة اليوربا

﴿فلما جاوزا قال لفتاه آتنا غداءنا لقد لقينا من سفرنا هذا نصبا﴾ [الكَهف: 62]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Nígbà tí àwọn méjèèjì ré kọjá (ibi tí odò méjì ti pàdé), ó sọ fún ọmọ-ọ̀dọ̀ rẹ̀ pé: "Fún wa ní oúnjẹ ọ̀sán wa. Dájúdájú a ti ko wàhálà nínú ìrìn-àjò wa yìí
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek