Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 15 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَسَلَٰمٌ عَلَيۡهِ يَوۡمَ وُلِدَ وَيَوۡمَ يَمُوتُ وَيَوۡمَ يُبۡعَثُ حَيّٗا ﴾
[مَريَم: 15]
﴿وسلام عليه يوم ولد ويوم يموت ويوم يبعث حيا﴾ [مَريَم: 15]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àlàáfíà ni fún un ní ọjọ́ tí wọ́n bí i, àti ní ọjọ́ tí ó máa kú àti ní ọjọ́ tí A óò gbé e dìde láàyè (ní Ọjọ́ Àjíǹde) |