Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 66 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَيَقُولُ ٱلۡإِنسَٰنُ أَءِذَا مَا مِتُّ لَسَوۡفَ أُخۡرَجُ حَيًّا ﴾
[مَريَم: 66]
﴿ويقول الإنسان أئذا ما مت لسوف أخرج حيا﴾ [مَريَم: 66]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ènìyàn ń wí pé: “Ṣé nígbà tí mo bá kú, Wọn yóò tún mú mi jáde láìpẹ́ ní alààyè?” |