Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 67 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿أَوَلَا يَذۡكُرُ ٱلۡإِنسَٰنُ أَنَّا خَلَقۡنَٰهُ مِن قَبۡلُ وَلَمۡ يَكُ شَيۡـٔٗا ﴾
[مَريَم: 67]
﴿أو لا يذكر الإنسان أنا خلقناه من قبل ولم يك شيئا﴾ [مَريَم: 67]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ṣé ènìyàn kò rántí pé dájúdájú Àwa ni A ṣẹ̀dá rẹ̀ tẹ́lẹ̀tẹ́lẹ̀ nígbà tí kò tí ì jẹ́ n̄ǹkan kan |