Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 80 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَنَرِثُهُۥ مَا يَقُولُ وَيَأۡتِينَا فَرۡدٗا ﴾
[مَريَم: 80]
﴿ونرثه ما يقول ويأتينا فردا﴾ [مَريَم: 80]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A ó sì jogún ohun t’ó ń wí fún un. Ó sì máa wá bá Wa ní òun nìkan |