Quran with Yoruba translation - Surah Maryam ayat 81 - مَريَم - Page - Juz 16
﴿وَٱتَّخَذُواْ مِن دُونِ ٱللَّهِ ءَالِهَةٗ لِّيَكُونُواْ لَهُمۡ عِزّٗا ﴾
[مَريَم: 81]
﴿واتخذوا من دون الله آلهة ليكونوا لهم عزا﴾ [مَريَم: 81]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọ́n sọ àwọn kan di ọlọ́hun lẹ́yìn Allāhu nítorí kí wọ́n lè fún wọn ní agbára |