Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 157 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿أُوْلَٰٓئِكَ عَلَيۡهِمۡ صَلَوَٰتٞ مِّن رَّبِّهِمۡ وَرَحۡمَةٞۖ وَأُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلۡمُهۡتَدُونَ ﴾
[البَقَرَة: 157]
﴿أولئك عليهم صلوات من ربهم ورحمة وأولئك هم المهتدون﴾ [البَقَرَة: 157]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn wọ̀nyẹn ni àforíjìn àti ìkẹ́ yó máa bẹ fún láti ọ̀dọ̀ Olúwa wọn. Àwọn wọ̀nyẹn, àwọn sì ni olùmọ̀nà |