Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 18 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿صُمُّۢ بُكۡمٌ عُمۡيٞ فَهُمۡ لَا يَرۡجِعُونَ ﴾
[البَقَرَة: 18]
﴿صم بكم عمي فهم لا يرجعون﴾ [البَقَرَة: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Adití, ayaya, afọ́jú ni wọ́n; nítorí náà wọn kò níí ṣẹ́rí padà |