Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 192 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿فَإِنِ ٱنتَهَوۡاْ فَإِنَّ ٱللَّهَ غَفُورٞ رَّحِيمٞ ﴾
[البَقَرَة: 192]
﴿فإن انتهوا فإن الله غفور رحيم﴾ [البَقَرَة: 192]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí wọ́n bá sì jáwọ́ (nínú ìbọ̀rìṣà), dájúdájú Allāhu ni Aláforíjìn, Àṣàkẹ́-ọ̀run |