Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 202 - البَقَرَة - Page - Juz 2
﴿أُوْلَٰٓئِكَ لَهُمۡ نَصِيبٞ مِّمَّا كَسَبُواْۚ وَٱللَّهُ سَرِيعُ ٱلۡحِسَابِ ﴾
[البَقَرَة: 202]
﴿أولئك لهم نصيب مما كسبوا والله سريع الحساب﴾ [البَقَرَة: 202]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn wọ̀nyẹn, tiwọn ni ìpín oore nípa ohun tí wọ́n ṣe níṣẹ́. Allāhu sì ni Olùyára níbi ìṣírò-iṣẹ́ |