Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 56 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿ثُمَّ بَعَثۡنَٰكُم مِّنۢ بَعۡدِ مَوۡتِكُمۡ لَعَلَّكُمۡ تَشۡكُرُونَ ﴾
[البَقَرَة: 56]
﴿ثم بعثناكم من بعد موتكم لعلكم تشكرون﴾ [البَقَرَة: 56]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Lẹ́yìn náà, A ji yín dìde lẹ́yìn ikú yín, nítorí kí ẹ lè dúpẹ́ (fún Allāhu) |