Quran with Yoruba translation - Surah Al-Baqarah ayat 99 - البَقَرَة - Page - Juz 1
﴿وَلَقَدۡ أَنزَلۡنَآ إِلَيۡكَ ءَايَٰتِۭ بَيِّنَٰتٖۖ وَمَا يَكۡفُرُ بِهَآ إِلَّا ٱلۡفَٰسِقُونَ ﴾
[البَقَرَة: 99]
﴿ولقد أنـزلنا إليك آيات بينات وما يكفر بها إلا الفاسقون﴾ [البَقَرَة: 99]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A ti sọ àwọn āyah tó yanjú kalẹ̀ fún ọ. Ẹnì kan kò níí ṣàì gbàgbọ́ nínú rẹ̀ àyàfi àwọn arúfin |