Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 103 - طه - Page - Juz 16
﴿يَتَخَٰفَتُونَ بَيۡنَهُمۡ إِن لَّبِثۡتُمۡ إِلَّا عَشۡرٗا ﴾
[طه: 103]
﴿يتخافتون بينهم إن لبثتم إلا عشرا﴾ [طه: 103]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn yó sì máa sọ̀rọ̀ ní jẹ́ẹ́jẹ́ láààrin ara wọn pé: "Ẹ̀yin kò gbé ilé ayé tayọ (ọjọ́) mẹ́wàá |