Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 111 - طه - Page - Juz 16
﴿۞ وَعَنَتِ ٱلۡوُجُوهُ لِلۡحَيِّ ٱلۡقَيُّومِۖ وَقَدۡ خَابَ مَنۡ حَمَلَ ظُلۡمٗا ﴾
[طه: 111]
﴿وعنت الوجوه للحي القيوم وقد خاب من حمل ظلما﴾ [طه: 111]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn ojú yó sì wólẹ̀ fún Alààyè, Alámòjúútó-ẹ̀dá. Dájúdájú ẹnikẹ́ni tí ó bá di àbòsí mẹ́rù ti pòfo |