Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 54 - طه - Page - Juz 16
﴿كُلُواْ وَٱرۡعَوۡاْ أَنۡعَٰمَكُمۡۚ إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَأٓيَٰتٖ لِّأُوْلِي ٱلنُّهَىٰ ﴾
[طه: 54]
﴿كلوا وارعوا أنعامكم إن في ذلك لآيات لأولي النهى﴾ [طه: 54]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ẹ jẹ, kí ẹ sì fi bọ́ àwọn ẹran-ọ̀sìn yín. Dájúdájú àwọn àmì wà nínú ìyẹn fún àwọn onílàákàyè |