Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 60 - طه - Page - Juz 16
﴿فَتَوَلَّىٰ فِرۡعَوۡنُ فَجَمَعَ كَيۡدَهُۥ ثُمَّ أَتَىٰ ﴾
[طه: 60]
﴿فتولى فرعون فجمع كيده ثم أتى﴾ [طه: 60]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Fir‘aon pẹ̀yìn dà. Ó sì sa ète rẹ̀ jọ mọ́ra wọn. Lẹ́yìn náà, ó dé (síbẹ̀) |