Quran with Yoruba translation - Surah Ta-Ha ayat 98 - طه - Page - Juz 16
﴿إِنَّمَآ إِلَٰهُكُمُ ٱللَّهُ ٱلَّذِي لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَۚ وَسِعَ كُلَّ شَيۡءٍ عِلۡمٗا ﴾
[طه: 98]
﴿إنما إلهكم الله الذي لا إله إلا هو وسع كل شيء علما﴾ [طه: 98]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ọlọ́hun yin ni Allāhu nìkan, kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Òun. Ó fi ìmọ̀ gbòòrò ju gbogbo n̄ǹkan |