Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 23 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿لَا يُسۡـَٔلُ عَمَّا يَفۡعَلُ وَهُمۡ يُسۡـَٔلُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 23]
﴿لا يسأل عما يفعل وهم يسألون﴾ [الأنبيَاء: 23]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Wọn kò níí bi (Allāhu) ní ìbéèrè nípa n̄ǹkan tí Ó ń ṣe. Àwọn ni wọ́n máa bi ní ìbéèrè (nípa iṣẹ́ ọwọ́ wọn) |