×

Ti o ba je pe awon olohun kan wa ninu sanmo ati 21:22 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Anbiya’ ⮕ (21:22) ayat 22 in Yoruba

21:22 Surah Al-Anbiya’ ayat 22 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 22 - الأنبيَاء - Page - Juz 17

﴿لَوۡ كَانَ فِيهِمَآ ءَالِهَةٌ إِلَّا ٱللَّهُ لَفَسَدَتَاۚ فَسُبۡحَٰنَ ٱللَّهِ رَبِّ ٱلۡعَرۡشِ عَمَّا يَصِفُونَ ﴾
[الأنبيَاء: 22]

Ti o ba je pe awon olohun kan wa ninu sanmo ati ile leyin Allahu, sanmo ati ile iba ti baje. Mimo ni fun Allahu, Oluwa Ite-ola, tayo ohun ti won n fi royin (Re)

❮ Previous Next ❯

ترجمة: لو كان فيهما آلهة إلا الله لفسدتا فسبحان الله رب العرش عما, باللغة اليوربا

﴿لو كان فيهما آلهة إلا الله لفسدتا فسبحان الله رب العرش عما﴾ [الأنبيَاء: 22]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Tí ó bá jẹ́ pé àwọn ọlọ́hun kan wà nínú sánmọ̀ àti ilẹ̀ lẹ́yìn Allāhu, sánmọ̀ àti ilẹ̀ ìbá ti bàjẹ́. Mímọ́ ni fún Allāhu, Olúwa Ìtẹ́-ọlá, tayọ ohun tí wọ́n ń fi ròyìn (Rẹ̀)
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek