Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 25 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَمَآ أَرۡسَلۡنَا مِن قَبۡلِكَ مِن رَّسُولٍ إِلَّا نُوحِيٓ إِلَيۡهِ أَنَّهُۥ لَآ إِلَٰهَ إِلَّآ أَنَا۠ فَٱعۡبُدُونِ ﴾
[الأنبيَاء: 25]
﴿وما أرسلنا من قبلك من رسول إلا نوحي إليه أنه لا إله﴾ [الأنبيَاء: 25]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A kò rán òjíṣẹ́ kan níṣẹ́ ṣíwájú rẹ àfi kí A fi ìmísí ránṣẹ́ sí i pé: “Dájúdájú kò sí ọlọ́hun tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Èmi (Allāhu). Nítorí náà, ẹ jọ́sìn fún Mi.” |