Quran with Yoruba translation - Surah Al-Anbiya’ ayat 75 - الأنبيَاء - Page - Juz 17
﴿وَأَدۡخَلۡنَٰهُ فِي رَحۡمَتِنَآۖ إِنَّهُۥ مِنَ ٱلصَّٰلِحِينَ ﴾
[الأنبيَاء: 75]
﴿وأدخلناه في رحمتنا إنه من الصالحين﴾ [الأنبيَاء: 75]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni A sì mú un wọ inú ìkẹ́ Wa. Dájúdájú ó wà nínú àwọn ẹni rere |