Quran with Yoruba translation - Surah Al-hajj ayat 68 - الحج - Page - Juz 17
﴿وَإِن جَٰدَلُوكَ فَقُلِ ٱللَّهُ أَعۡلَمُ بِمَا تَعۡمَلُونَ ﴾
[الحج: 68]
﴿وإن جادلوك فقل الله أعلم بما تعملون﴾ [الحج: 68]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí wọ́n bá sì jà ọ́ níyàn, sọ nígbà náà pé: "Allāhu nímọ̀ jùlọ nípa ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́ |