Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 29 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿وَقُل رَّبِّ أَنزِلۡنِي مُنزَلٗا مُّبَارَكٗا وَأَنتَ خَيۡرُ ٱلۡمُنزِلِينَ ﴾
[المؤمنُون: 29]
﴿وقل رب أنـزلني منـزلا مباركا وأنت خير المنـزلين﴾ [المؤمنُون: 29]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Olúwa mi, sọ̀ mí kalẹ̀ sí ibùsọ̀ ìbùkún. Ìwọ sì lóore jùlọ nínú àwọn amúnigúnlẹ̀.” |