Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 30 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿إِنَّ فِي ذَٰلِكَ لَأٓيَٰتٖ وَإِن كُنَّا لَمُبۡتَلِينَ ﴾
[المؤمنُون: 30]
﴿إن في ذلك لآيات وإن كنا لمبتلين﴾ [المؤمنُون: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú àwọn àmì wà nínú ìyẹn. Àwa sì ni À ń dán ẹ̀dá wò |