×

Ti o ba je pe (Allahu), Oba Ododo tele ife-inu won ni, 23:71 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah Al-Mu’minun ⮕ (23:71) ayat 71 in Yoruba

23:71 Surah Al-Mu’minun ayat 71 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 71 - المؤمنُون - Page - Juz 18

﴿وَلَوِ ٱتَّبَعَ ٱلۡحَقُّ أَهۡوَآءَهُمۡ لَفَسَدَتِ ٱلسَّمَٰوَٰتُ وَٱلۡأَرۡضُ وَمَن فِيهِنَّۚ بَلۡ أَتَيۡنَٰهُم بِذِكۡرِهِمۡ فَهُمۡ عَن ذِكۡرِهِم مُّعۡرِضُونَ ﴾
[المؤمنُون: 71]

Ti o ba je pe (Allahu), Oba Ododo tele ife-inu won ni, awon sanmo ati ile ati awon t’o wa ninu won iba kuku ti baje. Sugbon A mu isiti nipa oro ara won wa fun won ni, won si n gbunri kuro nibi isiti (ti A mu wa fun) won

❮ Previous Next ❯

ترجمة: ولو اتبع الحق أهواءهم لفسدت السموات والأرض ومن فيهن بل أتيناهم بذكرهم, باللغة اليوربا

﴿ولو اتبع الحق أهواءهم لفسدت السموات والأرض ومن فيهن بل أتيناهم بذكرهم﴾ [المؤمنُون: 71]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Tí ó bá jẹ́ pé (Allāhu), Ọba Òdodo tẹ̀lé ìfẹ́-inú wọn ni, àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ àti àwọn t’ó wà nínú wọn ìbá kúkú ti bàjẹ́. Ṣùgbọ́n A mú ìṣítí nípa ọ̀rọ̀ ara wọn wá fún wọn ni, wọ́n sì ń gbúnrí kúrò níbi ìṣítí (tí A mú wá fún) wọn
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek