Quran with Yoruba translation - Surah Al-Mu’minun ayat 81 - المؤمنُون - Page - Juz 18
﴿بَلۡ قَالُواْ مِثۡلَ مَا قَالَ ٱلۡأَوَّلُونَ ﴾
[المؤمنُون: 81]
﴿بل قالوا مثل ما قال الأولون﴾ [المؤمنُون: 81]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Rárá (wọn kò níí ṣe làákàyè, ṣebí) irú ohun tí àwọn ẹni àkọ́kọ́ wí ni àwọn náà wí |