Quran with Yoruba translation - Surah Al-Furqan ayat 35 - الفُرقَان - Page - Juz 19
﴿وَلَقَدۡ ءَاتَيۡنَا مُوسَى ٱلۡكِتَٰبَ وَجَعَلۡنَا مَعَهُۥٓ أَخَاهُ هَٰرُونَ وَزِيرٗا ﴾
[الفُرقَان: 35]
﴿ولقد آتينا موسى الكتاب وجعلنا معه أخاه هارون وزيرا﴾ [الفُرقَان: 35]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Dájúdájú A fún (Ànábì) Mūsā ní Tírà. A tún ṣe arákùnrin rẹ̀, Hārūn, ní amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ fún un |