Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 198 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿وَلَوۡ نَزَّلۡنَٰهُ عَلَىٰ بَعۡضِ ٱلۡأَعۡجَمِينَ ﴾
[الشعراء: 198]
﴿ولو نـزلناه على بعض الأعجمين﴾ [الشعراء: 198]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Tí ó bá jẹ́ pé A sọ̀ ọ́ kalẹ̀ fún apá kan àwọn elédè mìíràn ni |