Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 31 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿قَالَ فَأۡتِ بِهِۦٓ إِن كُنتَ مِنَ ٱلصَّٰدِقِينَ ﴾
[الشعراء: 31]
﴿قال فأت به إن كنت من الصادقين﴾ [الشعراء: 31]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Fir‘aon) wí pé: “Mú un wá nígbà náà tí ìwọ bá wà nínú àwọn olódodo.” |