Quran with Yoruba translation - Surah Ash-Shu‘ara’ ayat 30 - الشعراء - Page - Juz 19
﴿قَالَ أَوَلَوۡ جِئۡتُكَ بِشَيۡءٖ مُّبِينٖ ﴾
[الشعراء: 30]
﴿قال أو لو جئتك بشيء مبين﴾ [الشعراء: 30]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (Ànábì Mūsā) sọ pé: “Tí ó bá jẹ́ pé mo mú kiní kan t’ó yanjú wá fún ọ ńkọ́?” |