Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 65 - النَّمل - Page - Juz 20
﴿قُل لَّا يَعۡلَمُ مَن فِي ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلۡأَرۡضِ ٱلۡغَيۡبَ إِلَّا ٱللَّهُۚ وَمَا يَشۡعُرُونَ أَيَّانَ يُبۡعَثُونَ ﴾
[النَّمل: 65]
﴿قل لا يعلم من في السموات والأرض الغيب إلا الله وما يشعرون﴾ [النَّمل: 65]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Sọ pé: “Àwọn t’ó wà nínú àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ kò nímọ̀ ìkọ̀kọ̀ àfi Allāhu. Àti pé wọn kò sì mọ àsìkò wo ni A máa gbé àwọn òkú dìde.” |