Quran with Yoruba translation - Surah An-Naml ayat 75 - النَّمل - Page - Juz 20
﴿وَمَا مِنۡ غَآئِبَةٖ فِي ٱلسَّمَآءِ وَٱلۡأَرۡضِ إِلَّا فِي كِتَٰبٖ مُّبِينٍ ﴾
[النَّمل: 75]
﴿وما من غائبة في السماء والأرض إلا في كتاب مبين﴾ [النَّمل: 75]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé kò sí ohun ìkọ̀kọ̀ kan nínú sánmọ̀ àti ilẹ̀ àfi kí ó wà nínú àkọsílẹ̀ t’ó hàn kedere |