Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qasas ayat 52 - القَصَص - Page - Juz 20
﴿ٱلَّذِينَ ءَاتَيۡنَٰهُمُ ٱلۡكِتَٰبَ مِن قَبۡلِهِۦ هُم بِهِۦ يُؤۡمِنُونَ ﴾
[القَصَص: 52]
﴿الذين آتيناهم الكتاب من قبله هم به يؤمنون﴾ [القَصَص: 52]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn tí A fún ní Tírà ṣíwájú rẹ̀, wọ́n gba al-Ƙur’ān gbọ́ |