Quran with Yoruba translation - Surah Al-Qasas ayat 51 - القَصَص - Page - Juz 20
﴿۞ وَلَقَدۡ وَصَّلۡنَا لَهُمُ ٱلۡقَوۡلَ لَعَلَّهُمۡ يَتَذَكَّرُونَ ﴾
[القَصَص: 51]
﴿ولقد وصلنا لهم القول لعلهم يتذكرون﴾ [القَصَص: 51]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àti pé dájúdájú A ti ṣe àlàyé ọ̀rọ̀ náà fún wọn nítorí kí wọ́n lè lo ìrántí |