Quran with Yoruba translation - Surah Al-‘Ankabut ayat 66 - العَنكبُوت - Page - Juz 21
﴿لِيَكۡفُرُواْ بِمَآ ءَاتَيۡنَٰهُمۡ وَلِيَتَمَتَّعُواْۚ فَسَوۡفَ يَعۡلَمُونَ ﴾
[العَنكبُوت: 66]
﴿ليكفروا بما آتيناهم وليتمتعوا فسوف يعلمون﴾ [العَنكبُوت: 66]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni nítorí kí wọ́n lè ṣàì moore sí n̄ǹkan tí A fún wọn àti nítorí kí wọ́n lè jayékáyé. Nítorí náà, láìpẹ́ wọ́n máa mọ̀ |