×

Ti daadaa kan ba kan yin, o maa ko ibanuje ba won. 3:120 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah al-‘Imran ⮕ (3:120) ayat 120 in Yoruba

3:120 Surah al-‘Imran ayat 120 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 120 - آل عِمران - Page - Juz 4

﴿إِن تَمۡسَسۡكُمۡ حَسَنَةٞ تَسُؤۡهُمۡ وَإِن تُصِبۡكُمۡ سَيِّئَةٞ يَفۡرَحُواْ بِهَاۖ وَإِن تَصۡبِرُواْ وَتَتَّقُواْ لَا يَضُرُّكُمۡ كَيۡدُهُمۡ شَيۡـًٔاۗ إِنَّ ٱللَّهَ بِمَا يَعۡمَلُونَ مُحِيطٞ ﴾
[آل عِمران: 120]

Ti daadaa kan ba kan yin, o maa ko ibanuje ba won. Ti aburu kan ba si sele si yin, won maa dunnu si i. Ti eyin ba se suuru, ti e si sora (fun won), ete won ko nii ko inira kan kan ba yin. Dajudaju Allahu ni Alamotan nipa ohun ti won n se nise

❮ Previous Next ❯

ترجمة: إن تمسسكم حسنة تسؤهم وإن تصبكم سيئة يفرحوا بها وإن تصبروا وتتقوا, باللغة اليوربا

﴿إن تمسسكم حسنة تسؤهم وإن تصبكم سيئة يفرحوا بها وإن تصبروا وتتقوا﴾ [آل عِمران: 120]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Tí dáadáa kan bá kàn yín, ó máa kó ìbànújẹ́ bà wọn. Tí aburú kan bá sì ṣẹlẹ̀ si yín, wọ́n máa dunnú sí i. Tí ẹ̀yin bá ṣe sùúrù, tí ẹ sì ṣọ́ra (fún wọn), ète wọn kò níí kó ìnira kan kan ba yín. Dájúdájú Allāhu ni Alámọ̀tán nípa ohun tí wọ́n ń ṣe níṣẹ́
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek