×

Dajudaju A o maa dan yin wo ninu dukia yin ati emi 3:186 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah al-‘Imran ⮕ (3:186) ayat 186 in Yoruba

3:186 Surah al-‘Imran ayat 186 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 186 - آل عِمران - Page - Juz 4

﴿۞ لَتُبۡلَوُنَّ فِيٓ أَمۡوَٰلِكُمۡ وَأَنفُسِكُمۡ وَلَتَسۡمَعُنَّ مِنَ ٱلَّذِينَ أُوتُواْ ٱلۡكِتَٰبَ مِن قَبۡلِكُمۡ وَمِنَ ٱلَّذِينَ أَشۡرَكُوٓاْ أَذٗى كَثِيرٗاۚ وَإِن تَصۡبِرُواْ وَتَتَّقُواْ فَإِنَّ ذَٰلِكَ مِنۡ عَزۡمِ ٱلۡأُمُورِ ﴾
[آل عِمران: 186]

Dajudaju A o maa dan yin wo ninu dukia yin ati emi yin. Dajudaju eyin yoo maa gbo opolopo oro ipalara lati odo awon ti A fun ni tira siwaju yin ati awon osebo. Ti eyin ba se suuru, ti e si beru (Allahu), dajudaju iyen wa ninu awon ipinnu oro t’o pon dandan

❮ Previous Next ❯

ترجمة: لتبلون في أموالكم وأنفسكم ولتسمعن من الذين أوتوا الكتاب من قبلكم ومن, باللغة اليوربا

﴿لتبلون في أموالكم وأنفسكم ولتسمعن من الذين أوتوا الكتاب من قبلكم ومن﴾ [آل عِمران: 186]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
Dájúdájú A ó máa dan yín wò nínú dúkìá yín àti ẹ̀mí yín. Dájúdájú ẹ̀yin yóò máa gbọ́ ọ̀pọ̀lọ́pọ̀ ọ̀rọ̀ ìpalára láti ọ̀dọ̀ àwọn tí A fún ní tírà ṣíwájú yín àti àwọn ọ̀ṣẹbọ. Tí ẹ̀yin bá ṣe sùúrù, tí ẹ sì bẹ̀rù (Allāhu), dájúdájú ìyẹn wà nínú àwọn ìpinnu ọ̀rọ̀ t’ó pọn dandan
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek