Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 2 - آل عِمران - Page - Juz 3
﴿ٱللَّهُ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ ٱلۡحَيُّ ٱلۡقَيُّومُ ﴾
[آل عِمران: 2]
﴿الله لا إله إلا هو الحي القيوم﴾ [آل عِمران: 2]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Allāhu, kò sí ọlọ́hun kan tí ìjọ́sìn tọ́ sí àfi Òun, Alààyè, Alámòjúútó-ẹ̀dá |