×

ni isaaju. Imona si ni fun awon eniyan.1 O tun so oro-ipinya 3:4 Yoruba translation

Quran infoYorubaSurah al-‘Imran ⮕ (3:4) ayat 4 in Yoruba

3:4 Surah al-‘Imran ayat 4 in Yoruba (اليوربا)

Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 4 - آل عِمران - Page - Juz 3

﴿مِن قَبۡلُ هُدٗى لِّلنَّاسِ وَأَنزَلَ ٱلۡفُرۡقَانَۗ إِنَّ ٱلَّذِينَ كَفَرُواْ بِـَٔايَٰتِ ٱللَّهِ لَهُمۡ عَذَابٞ شَدِيدٞۗ وَٱللَّهُ عَزِيزٞ ذُو ٱنتِقَامٍ ﴾
[آل عِمران: 4]

ni isaaju. Imona si ni fun awon eniyan.1 O tun so oro-ipinya (oro t’o n sepinya laaarin ododo ati iro) kale.2 Dajudaju awon t’o sai gbagbo ninu awon ayah Allahu, iya t’o le n be fun won. Allahu si ni Alagbara, Olugbesan

❮ Previous Next ❯

ترجمة: من قبل هدى للناس وأنـزل الفرقان إن الذين كفروا بآيات الله لهم, باللغة اليوربا

﴿من قبل هدى للناس وأنـزل الفرقان إن الذين كفروا بآيات الله لهم﴾ [آل عِمران: 4]

Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni
ní ìṣaájú. Ìmọ̀nà sì ni fún àwọn ènìyàn.1 Ó tún sọ ọ̀rọ̀-ìpínyà (ọ̀rọ̀ t’ó ń ṣèpínyà láààrin òdodo àti irọ́) kalẹ̀.2 Dájúdájú àwọn t’ó ṣàì gbàgbọ́ nínú àwọn āyah Allāhu, ìyà t’ó le ń bẹ fún wọn. Allāhu sì ni Alágbára, Olùgbẹ̀san
❮ Previous Next ❯

Verse in more languages

Transliteration Bangla Bosnian German English Persian French Hindi Indonesian Kazakh Dutch Russian Spanish Turkish Urdu Uzbek