Quran with Yoruba translation - Surah al-‘Imran ayat 94 - آل عِمران - Page - Juz 4
﴿فَمَنِ ٱفۡتَرَىٰ عَلَى ٱللَّهِ ٱلۡكَذِبَ مِنۢ بَعۡدِ ذَٰلِكَ فَأُوْلَٰٓئِكَ هُمُ ٱلظَّٰلِمُونَ ﴾
[آل عِمران: 94]
﴿فمن افترى على الله الكذب من بعد ذلك فأولئك هم الظالمون﴾ [آل عِمران: 94]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Nítorí náà, ẹnikẹ́ni tí ó bá dá àdápa irọ́ mọ́ Allāhu lẹ́yìn ìyẹn, àwọn wọ̀nyẹn ni alábòsí |