Quran with Yoruba translation - Surah As-Sajdah ayat 18 - السَّجدة - Page - Juz 21
﴿أَفَمَن كَانَ مُؤۡمِنٗا كَمَن كَانَ فَاسِقٗاۚ لَّا يَسۡتَوُۥنَ ﴾
[السَّجدة: 18]
﴿أفمن كان مؤمنا كمن كان فاسقا لا يستوون﴾ [السَّجدة: 18]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Ǹjẹ́ ẹni t’ó jẹ́ onígbàgbọ́ òdodo dà bí ẹni t’ó jẹ́ òbìlẹ̀jẹ́ bí? Wọn kò dọ́gba |