Quran with Yoruba translation - Surah Saba’ ayat 11 - سَبإ - Page - Juz 22
﴿أَنِ ٱعۡمَلۡ سَٰبِغَٰتٖ وَقَدِّرۡ فِي ٱلسَّرۡدِۖ وَٱعۡمَلُواْ صَٰلِحًاۖ إِنِّي بِمَا تَعۡمَلُونَ بَصِيرٞ ﴾
[سَبإ: 11]
﴿أن اعمل سابغات وقدر في السرد واعملوا صالحا إني بما تعملون بصير﴾ [سَبإ: 11]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni (A sọ fún un) pé ṣe àwọn ẹ̀wù irin t’ó máa bo ara, ṣe òrùka-ọrùn fún ẹ̀wù irin náà níwọ̀n-níwọ̀n. Kí ẹ sì ṣe rere. Dájúdájú Èmi ni Olùríran nípa ohun tí ẹ̀ ń ṣe níṣẹ́ |