Quran with Yoruba translation - Surah Saba’ ayat 38 - سَبإ - Page - Juz 22
﴿وَٱلَّذِينَ يَسۡعَوۡنَ فِيٓ ءَايَٰتِنَا مُعَٰجِزِينَ أُوْلَٰٓئِكَ فِي ٱلۡعَذَابِ مُحۡضَرُونَ ﴾
[سَبإ: 38]
﴿والذين يسعون في آياتنا معاجزين أولئك في العذاب محضرون﴾ [سَبإ: 38]
Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni Àwọn t’ó ń ṣe iṣẹ́ aburú nípa àwọn āyah Wa, (tí wọ́n lérò pé) àwọn mórí bọ́ nínú ìyà; àwọn wọ̀nyẹn ni wọ́n máa mú wá sínú Iná.” |